Du er ikke logget ind
Beskrivelse
Ó j¿¿ ohùn ìdùnnú fún mí púp¿¿ láti k¿ ìwé àkój¿p¿¿ ewì yìí. A k¿ ìwé ewì yìí ni àsìkò tí oríl¿¿-èdè Nàíjíríà pé ¿g¿¿ta ¿dún láti ¿e àyàjó¿ ¿j¿¿ ìbí r¿¿ náà; ti wón ¿e À¿EY¿RÍ ÒMÌNIRA ¿G¿TA ¿DÚN ORÍL¿¿ ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ. Àw¿n ewì j¿ ohun àbálàye tí ó j¿ ¿m¿ Yorùbá lógún. Ní ayé àtij¿¿ ní ilè Yorùbá, ò un ni àw¿n bàbá-¿lá wa máa ¿ lò fún ìmò¿, ìmò¿ràn àti ¿¿k¿¿, ¿ùgbó¿n won kìí k¿¿¿ síl¿¿ nítorí pé, w¿n kò ní ìmò¿ mò¿ó¿k¿¿mò¿ó¿kà rárá. Orísírísí ewì ni ó wa, orísírísí ¿¿nà ni a sì lè pín ewì sí. Èrò ¿kàn mí ní pé a ó gbàdùn ìwé àkój¿p¿¿ ewì yìí. "S¿¿r¿¿ Sókè!" ni àk¿lé Ìwé Ì¿ípayá Ewi Yorùbá yìí (Speak Up!). Àk¿lé ìwé yìí j¿ jáde nínú ¿¿r¿¿ àw¿n ¿¿d¿¿ Nàíjíríà (A popular phrase that has informally become the name of the millennial slang of generations in Nigeria). Àw¿n ¿¿d¿¿ ¿e ìw¿de #EndSARS ní Oríl¿¿-èdè Nàíjíríà: ní ìpínlè Èkó, Ekiti, ¿¿y¿¿, Ondo, Osun, Kwara ati Abuja lati bá àw¿n olórí àti àw¿n ¿m¿ ilu s¿¿r¿¿ ní ¿dún 2020. Kí ni ìtum¿¿ "S¿¿r¿¿ Sókè" àti Ìw¿¿de tí àw¿n ¿¿d¿¿ n ¿e àgbékal¿¿ r¿¿ yìí? Wó¿n fi Ìw¿¿de #EndSARS yìí s¿ pé kí àw¿n ¿l¿pa má ¿e pa àw¿n ará ìlú m¿¿, pàtàkì jù l¿ àw¿n ¿¿d¿¿ àti pé kí olúkúlùkù s¿ àw¿n è¿dùn ¿kàn w¿n gbogbo jáde ni oríl¿¿-èdè NÀÍJÍRÍÀ.