Du er ikke logget ind
Beskrivelse
EWÌ S¿¿R¿¿ SO¿KE¿: Ó j¿¿ ohùn ìdùnnú fún mí púp¿¿ láti k¿ ìwé àkój¿p¿¿ ewì yìí. Àw¿n ewì j¿ ohun àbálàye tí ó j¿ ¿m¿ Yorùbá lógún. Ní ayé àtij¿¿ ní ilè Yorùbá, ò un ni àw¿n bàbá-¿lá wa máa ¿ lò fún ìmò¿, ìmò¿ràn àti ¿¿k¿¿, ¿ùgbó¿n won kìí k¿¿¿ síl¿¿ nítorí pé, w¿n kò ní ìmò¿ mò¿ó¿k¿¿mò¿ó¿kà rárá. Orísírísí àw¿n ewì ni ó wa, Èrò ¿kàn mí ní pé a ó gbàdùn ìwé àkój¿p¿¿ ewì yìí. "Ewì S¿¿r¿¿ Sókè!" ni àk¿lé Ìwé Ì¿ípayá Ewi Yorùbá yìí (Poetry On Speak Up!). Àk¿lé ìwé yìí j¿ jáde nínú ¿¿r¿¿ àw¿n ¿¿d¿¿ Nàíjíríà (A popular phrase that has informally become the name of the millennial slang of generations in Nigeria). Àw¿n ¿¿d¿¿ ¿e ìw¿de #EndSARS ní Oríl¿¿-èdè Nàíjíríà: ní ìpínlè Èkó, Ekiti, ¿¿y¿¿, Ondo, Osun, Kwara ati Abuja lati bá àw¿n olórí àti àw¿n ¿m¿ ilu s¿¿r¿¿ ní ¿dún 2020. Kí ni ìtum¿¿ "S¿¿r¿¿ Sókè" àti Ìw¿¿de tí àw¿n ¿¿d¿¿ n ¿e àgbékal¿¿ r¿¿ yìí? Wó¿n fi Ìw¿¿de #EndSARS yìí s¿ pé kí àw¿n ¿l¿pa má ¿e pa àw¿n ará ìlú m¿¿, pàtàkì jù l¿ àw¿n ¿¿d¿¿ àti pé kí olúkúlùkù s¿ àw¿n è¿dùn ¿kàn w¿n gbogbo jáde ni oríl¿¿-èdè NÀÍJÍRÍÀ. Naijiria ni orílè-èdè tí ó ní ibùgbé púpò jùl¿ ní Afrika, ó tún j¿¿ ìk¿j¿ ní àgbáyé, b¿ si ní ó j¿¿ oríl¿¿-èdè tó ní àw¿n ènìyàn dúdú jùl¿ pè¿lú.